Ìròyìn Ijoba apapo yoo gbe awon eniyan marun ti a fi oju won mo ninu ikolu to sele ni Ile ijọsin Katoliki Owo si ile ejo.