Alaye iṣẹ NATO àti European Union (EU) Ti ń pọ̀ sí ìṣọ̀kan láti dá “ogiri ààbò” lórí àwọn ọkọ ofurufu aláìlórúkọ tó lè ṣe ewu.
Ìròyìn Àwọ́n Papa Òfurufú ilẹ̀ Denmark Tiì Pa Dé Lẹ́yìn Ìkọlù Dírónù “Hybrid”, Minisita Ṣàlàyé Pé Kò Ní Ìbáṣepọ̀ Pẹ̀lú Rọ́ṣíà