Àṣà Àwọn ọba ibílẹ̀ ń wá ìpò nínú òfin orílẹ̀-èdè, wọ́n ní ìdí wọn ni láti ṣe ìtìlẹ́yìn fún àwọn olóṣèlú, kì í ṣe láti bá wọn ṣọ̀rọ̀ agbára.